Psalms 137:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, ranti ohun tí àwọn ará Edomu ṣe nígbà tí Jerusalẹmu bọ́ sọ́wọ́ ọ̀tá, tí wọn ń pariwo pé, “Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o títí dé ìpìlẹ̀ rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, ranti ọjọ Jerusalemu lara awọn ọmọ Edomu, awọn ẹniti nwipe, Wó o palẹ, wó o palẹ, de ipilẹ rẹ̀!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA rántí ọjọ́ Jérúsálẹ́mù, lára àwọn ọmọ Édómù, àwọn ẹni tí ń wí pé, wó o palẹ̀, wó o palẹ̀ de ìpílẹ̀ Rẹ̀!