bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 137:9
Psalms 137:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bá kó àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ rẹ, tí ó ṣán wọn mọ́ àpáta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún li ẹniti o mu, ti o si fi ọmọ wẹwẹ rẹ ṣán okuta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ní fún ẹni tí ó mú tí ó sì fi ọmọ wẹ́wẹ́ Rẹ̀ ṣán òkúta.