Psalms 138:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, gbogbo ọba ayé ni yóo máa yìn ọ́, nítorí pé wọ́n ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ọba aiye yio yìn ọ, Oluwa, nigbati nwọn ba gbọ́ ọ̀rọ ẹnu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọba ayé yóò yìn ọ́, OLÚWA, ní ìgbà tí wọn bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu Rẹ