Psalms 139:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí á tó dá mi tán ni o ti rí mi, o ti kọ iye ọjọ́ tí a pín fún mi sinu ìwé rẹ, kí ọjọ́ ayé mi tilẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ rárá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju rẹ ti ri ohun ara mi ti o wà laipé: a ti ninu iwe rẹ ni a ti kọ gbogbo wọn si, li ojojumọ li a nda wọn, nigbati ọkan wọn kò ti isi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú Rẹ̀ ti rí ohun ara mi tí ó wà láìpé: àti nínú ìwé Rẹ ni a ti kọ gbogbo wọn sí, ní ojojumọ́ ni a ń dá wọn, nígbà tí ọ̀kan wọn kò tí i sí.