Psalms 14:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣé gbogbo àwọn aṣebi kò gbọ́n ni? Àwọn tí ń jẹ eniyan mi bí ẹni jẹun, àwọn tí kì í ké pe OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ti nṣiṣẹ ẹ̀ṣẹ kò ha ni ìmọ? awọn ẹniti njẹ enia mi bi ẹni jẹun, nwọn kò si kepè Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ olùṣe búburú kò ha ní kọ́ ẹ̀kọ́: àwọn tí ó ń pa ènìyàn mí jẹ bí ẹníjẹ àkàrà tí wọn kò sì ké pe OLÚWA?