Psalms 14:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìbá ti dára tó kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá! Nígbà tí OLUWA bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada, Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tani yio fi igbala fun Israeli lati Sioni jade wá! nigbati Oluwa ba mu ikólọ awọn enia rẹ̀ pada bọ̀, Jakobu yio yọ̀, inu Israeli yio si dùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbàlà àwọn Ísírẹ́lì yóò ti Síónì wá! Nígbà tí OLÚWA bá mú ìkólọ àwọn ènìyàn Rẹ̀ padà, jẹ́ kí Jákọ́bù kí ó yọ̀, kí inú Ísírẹ́lì kí ó dùn!