Psalms 141:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí àwọn eniyan burúkú ṣubú sinu àwọ̀n ara wọn, kí èmi sì lọ láìfarapa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki awọn enia buburu ki o bọ́ sinu àwọn ara wọn, nigbati emi ba kọja lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn ẹni búburú ṣubú sínú àwọ̀n ara wọn, nígbà tí èmi kọjá láìléwu.