Psalms 141:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N ò kọ̀ kí ẹni rere bá mi wí, n ò kọ̀ kí ó nà mí; kí ó ṣá ti fi ìfẹ́ bá mi wí. Ṣugbọn má jẹ́ kí eniyan burúkú tilẹ̀ ta òróró sí mi lórí, nítorí pé nígbàkúùgbà ni mò ń fi adura tako ìwà ibi wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki olododo ki o lù mi; iṣeun ni yio jasi: jẹ ki o si ba mi wi; ororo daradara ni yio jasi, ti kì yio fọ́ mi lori: sibẹ adura mi yio sa wà nitori jamba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí olódodo lù mí: ìṣeun ni ó jẹ́: jẹ́ kí ó bá mi wí, ó jẹ́ òróró ní orí mi. Tí kì yóò fọ́ mí ní orí. Ṣíbẹ̀ àdúrà mi wá láí sí ìṣe àwọn olùṣe búburú