Psalms 141:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pa mí mọ́ ninu ewu tàkúté, ati ti okùn tí àwọn aṣebi dẹ sílẹ̀ dè mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pa mi mọ́ kuro ninu okùn ti nwọn dẹ silẹ fun mi, ati ikẹkùn awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pa mí mọ́ kúrò nínú okùn tí wọn ti dẹ sílẹ̀ fún mi, kúrò nínú ìdẹkùn tí àwọn olùṣe búburú ti dẹ sílẹ̀.