Psalms 142:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́, kí n lè yin orúkọ rẹ lógo. Àwọn olódodo yóo yí mi ká, nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mu ọkàn mi jade kuro ninu tubu, ki emi ki o le ma yìn orukọ rẹ; awọn olododo yio yi mi ka kiri; nitori iwọ o fi ọ̀pọlọpọ ba mi ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mú mi jáde kúrò nínú túbú, kí èmi lè máa yin orúkọ Rẹ. Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò péjọ nípa mi nítorí iwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ba mi ṣe.