Psalms 143:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, pa àwọn ọ̀tá mi, kí o sì pa gbogbo àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi run, nítorí pé iranṣẹ rẹ ni mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu ãnu rẹ ke awọn ọta mi kuro, ki o si run gbogbo awọn ti nni ọkàn mi lara: nitori pe iranṣẹ rẹ li emi iṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà, ké àwọn ọ̀ta mi kúrò, run gbogbo àwọn ọ̀tá mi, nítorí èmi ni ìránṣẹ́ Rẹ.