Psalms 143:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀tá ti lé mi bá, ó ti lù mí bolẹ̀; ó jù mí sinu òkùnkùn, bí ẹni tí ó ti kú tipẹ́tipẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti ọta ti ṣe inunibini si ọkàn mi; o ti lù ẹmi mi bolẹ; o ti mu mi joko li òkunkun, bi awọn ti o ti kú pẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀ta ń lé pa mi, ó fún mi pa mọ́ ilẹ̀; ó mú mi gbé nínú òkùnkùn bí àwọn tí ó ti kú ti pẹ́.