Psalms 143:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sì; ọkàn mi sì pòrúúruù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li ẹmi mi ṣe rẹ̀wẹsi ninu mi; òfo fò aiya mi ninu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ẹ̀mí mi ṣàárẹ̀ nínú mi; ọkàn mi tí ó wà nínú mi dààmú.