Psalms 144:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbà mí lọ́wọ́ idà ìkà, gbà mí lọ́wọ́ àwọn àjèjì, tí ẹnu wọ́n kún fún irọ́, tí ọwọ́ ọ̀tún wọn sì kún fún èké.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yọ mi, ki o si gbà mi lọwọ awọn ọmọ àjeji, ẹnu ẹniti nsọ̀rọ asan, ati ọwọ ọtún wọn jẹ ọwọ ọtún eke:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbàmí kí ó sì yọ mí nínú ewu kúrò lọ́wọ́ àwọn ọmọ àjèjì tí ẹnu wọn kún fún èké, tí ọwọ́ ọ̀tún wọn jẹ́ ọwọ́ ọ̀tún èké.