Psalms 144:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí àká wa kún fún oniruuru oúnjẹ, kí àwọn aguntan wa bí ẹgbẹẹgbẹrun, àní, ẹgbẹẹgbaarun ninu pápá oko wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki aká wa ki o le kún, ki o ma funni li oniruru iṣura: ki awọn agutan wa ki o ma bi ẹgbẹgbẹrun ati ẹgbẹgbẹrun mẹwa ni igboro wa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àká wa yóò kún pẹ̀lú gbogbo onírúurú oúnjẹ àgùntàn wa yóò pọ̀ si ní ẹgbẹ̀rún, ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ní oko wa: