Psalms 145:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìjọba ayérayé ni ìjọba rẹ, yóo sì máa wà láti ìran dé ìran. Olóòótọ́ ni OLUWA ninu gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀, olóore ọ̀fẹ́ sì ni ninu gbogbo ìṣe rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ijọba rẹ ijọba aiye-raiye ni, ati ijọba rẹ lati iran-diran gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjọba Rẹ ìjọba ayérayé ni, àti ìjọba Rẹ wà ní gbogbo ìran-díran.