Psalms 145:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA gbé gbogbo àwọn tí ń ṣubú lọ dìde, ó sì gbé gbogbo àwọn tí a tẹrí wọn ba nàró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa mu gbogbo awọn ti o ṣubu ró; o si gbé gbogbo awọn ti o tẹriba dide.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA mú gbogbo àwọn tí ó ṣubú ró ó sì gbé gbogbo àwọn tí ó tẹríba dìde.