Psalms 145:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ń tẹ́ ìfẹ́ àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ lọ́rùn; ó ń gbọ́ igbe wọn, ó sì ń gbà wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio mu ifẹ awọn ti mbẹ̀ru rẹ̀ ṣẹ: yio gbọ́ igbe wọn pẹlu, yio si gbà wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó mú ìfẹ́ àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀ ṣẹ; ó gbọ́ igbe wọn, ó sì gbà wọ́n.