Psalms 146:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọlọrun tí ó dá ọ̀run ati ayé, òkun ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀; Ọlọrun tíí máa ń pa àdéhùn rẹ̀ mọ́ títí lae,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o da ọrun on aiye, okun ati ohun ti o wà ninu wọn: ẹniti o pa otitọ mọ́ titi aiye:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn OLÚWA, tí ó pa òtítọ́ mọ́ títí láéláé