Psalms 147:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn inú OLUWA dùn sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, àwọn tí ó ní ìrètí ninu ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa nṣe inudidùn si awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, si awọn ti nṣe ireti ãnu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ní ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀, sí àwọn tí ó ní ìrètí nínú àánú Rẹ̀.