Psalms 147:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó fún ẹnubodè rẹ ní agbára, ó sì bukun àwọn tí ń gbé inú rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti o ti mu ọpá-idabu ẹnu-bode rẹ le; o ti busi i fun awọn ọmọ rẹ ninu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ó ti mú ọ̀pá ìdábùú ìbodè Rẹ̀ lágbára; Òun sì ti bùkún fún àwọn ọmọ Rẹ̀ nínú Rẹ