Psalms 147:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ń tu àwọn tí ọkàn wọn bàjẹ́ ninu, ó sì ń dí ọgbẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O mu awọn onirora aiya lara da: o di ọgbẹ wọn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wo àwọn tí ọkàn wọ́n bajẹ́ sàn ó sì di ọgbẹ́ wọn.