bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 147:9
Psalms 147:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òun ni ó ń fún àwọn ẹranko ní oúnjẹ, tí ó sì ń bọ́ ọmọ ẹyẹ ìwò, tí ó ń ké.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O fi onjẹ ẹranko fun u ati fun ọmọ iwò ti ndún.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó pèṣè oúnjẹ fún àwọn ẹranko àti fún awọn ọmọ àdàbà ní ìgbà tí wọ́n bá ń ké.