Psalms 148:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ yìn ín, ẹ̀yin ọba ayé ati gbogbo orílẹ̀-èdè, ẹ̀yin ìjòyè ati gbogbo onídàájọ́ ayé;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọba aiye, ati gbogbo enia; ọmọ-alade, ati gbogbo onidajọ aiye;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọba ayé àti ènìyàn áye gbogbo àwọn ọmọ aládé àti gbogbo àwọn onídájọ́ ayé,