Psalms 148:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ti fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára, ó sì fún àwọn eniyan rẹ̀ mímọ́ ní ìyìn; ó fún àwọn eniyan Israẹli, tí ó wà lẹ́bàá ọ̀dọ̀ rẹ̀. Ẹ yin OLUWA!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si gbé iwo kan soke fun awọn enia rẹ̀, iyìn fun gbogbo enia mimọ́ rẹ̀; ani awọn ọmọ Israeli, awọn enia ti o sunmọ ọdọ rẹ̀. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì gbé ìwo kan sókè fún àwọn ènìyàn Rẹ̀, ìyìn fún gbogbo ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ àní fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn ènìyàn tí ó súnmọ́ ọ̀dọ̀ Rẹ̀. Ẹ fi ìyìn fún OLÚWA.