Psalms 149:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí Israẹli máa yọ̀ ninu Ẹlẹ́dàá rẹ̀, kí àwọn ọmọ Sioni máa fò fún ayọ̀ pé àwọn ní Ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki Israeli ki o yọ̀ si ẹniti o dá a; jẹ ki awọn ọmọ Sioni ki o kún fun ayọ̀ si Ọba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí Ísírẹ́lì kí ó ní inú dídùn sí ẹni tí ó dá a jẹ́ kí àwọn ọmọ Síónì kí ó ní ayọ̀ nínú ọba wọn.