Psalms 149:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí àwọn olódodo máa ṣògo ninu ọlá; kí wọ́n máa kọrin ayọ̀ lórí ibùsùn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki awọn enia mimọ́ ki o kún fun ayọ̀ ninu ogo; ki nwọn ki o mã kọrin kikan lori ẹni wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mímọ́ kí ó yọ̀ nínú ọlá Rẹ̀ kí wọn kí ó máa kọrin fún ayọ̀ ní orí ibùsùn wọn.