Psalms 149:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀. Ògo gbogbo àwọn olódodo nìyí. Ẹ yin OLUWA!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati ṣe idajọ wọn, ti a ti kọwe rẹ̀, ọlá yi ni gbogbo enia mimọ́ rẹ̀ ni. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ṣe ìdájọ́ tí àkọsílẹ̀ Rẹ̀ sí wọn èyí ni ògo àwọn ènìyàn mímọ́ Rẹ̀. Ẹ fi ìyìn fún OLÚWA.