Psalms 17:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn ń lépa mi; wọ́n sì ti yí mi ká báyìí; wọn ń ṣọ́ bí wọn ó ṣe bì mí ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti yi wa ká nisisiyi ninu ìrin wa; nwọn ti gbé oju wọn le ati wọ́ wa silẹ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì mú mi mọ́lẹ̀, wọ́n sì yí mi ká, pẹ̀lú ojú ìṣọ́ra láti sọ́ mi sílẹ̀.