Psalms 17:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dàbí kinniun tí ó ṣetán láti pa ẹran jẹ, àní bí ọmọ kinniun tí ó ba ní ibùba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi kiniun ti nṣe iwọra si ohun ọdẹ rẹ̀, ati bi ọmọ kiniun ti o mba ni ibi ìkọkọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn dà bí i kìnnìún tí ebi ń pa fún ìjẹ, àní bí Kìnnìún ńlá tí ó ń ba níbi ìkọ̀kọ̀.