Psalms 17:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn lọ́nà ìyanu, fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ gba àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ kúrò lọ́wọ́ àwọn tí ó gbógun tì wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fi iṣeun ifẹ iyanu rẹ hàn, iwọ ti o fi ọwọ ọtún rẹ gbà awọn ti o gbẹkẹle ọ là, lọwọ awọn ti o dide si wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi ìyanu ìfẹ́ ńlá Rẹ hàn ìwọ tí ó ń pamọ́ ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ àwọn tí ó wá ìsádi nínú Rẹ kúrò ní ọwọ́ ọ̀ta wọn.