Psalms 18:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ta ọfà rẹ̀ jáde, ó sì fọ́n wọn ká, ó jẹ́ kí mànàmáná kọ, ó sì tú wọn ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lõtọ, o rán ọfa rẹ̀ jade, o si tú wọn ká: ọ̀pọlọpọ manamana li o si fi ṣẹ́ wọn tũtu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ta àwọn ọfà Rẹ̀, ó sì tú àwọn ọ̀ta náà ká, ọfà mọ̀nàmọ́ná ńlá sì dà wọ́n rú.