Psalms 18:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi tí ó lágbára, ati lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra mi; nítorí wọ́n lágbára jù mí lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O gbà mi lọwọ ọta mi alagbara, ati lọwọ awọn ti o korira mi; nitori nwọn li agbara jù mi lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ ọ̀ta mi alágbára, láti ọwọ́ àwọn ọ̀ta, ti ó lágbára jù fún mi.