Psalms 18:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé gbogbo òfin rẹ̀ ni mo tẹ̀lé, n kò sì yà kúrò ninu ìlànà rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe gbogbo idajọ rẹ̀ li o wà niwaju mi, bẹ̃li emi kò si yẹ̀ ofin rẹ̀ kuro lọdọ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo òfin Rẹ̀ ni ó wà níwájú mi; èmi kò sì yípadà kúrò nínú ìlànà Rẹ̀.