Psalms 18:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pẹlu ìrànlọ́wọ́ rẹ̀, mo lè run ọ̀wọ́ àwọn ọmọ ogun, àní, pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun mi, mo lè fo odi ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe pẹlu rẹ emi sure là inu ogun lọ: ati pẹlu Ọlọrun mi emi fò odi kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Rẹ̀, èmi ṣare la ogun lọ; pẹ̀lú Ọlọ́run mi mo lè fo odi kan