Psalms 18:43 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tẹ̀ àwọn eniyan, o fi mí ṣe olórí àwọn orílẹ̀-èdè; àwọn orílẹ̀-èdè tí n kò mọ̀ rí sì ń sìn mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti yọ mi kuro ninu ìja awọn enia; iwọ fi mi jẹ olori awọn orilẹ-ède: enia ti emi kò ti mọ̀, yio si ma sìn mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ti gbà mí lọ́wọ́ ìkọlù àwọn ènìyàn; Ìwọ ti fi mí ṣe olórí àwọn orílẹ́ èdè; àwọn ènìyàn ti èmi kò mọ, yóò sì máa sìn mí.