Psalms 18:44 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí wọ́n bá ti gbúròó mi ni wọ́n ń gbọ́ràn sí mi lẹ́nu; àwọn àjèjì ń fi ìbẹ̀rùbojo tẹríba, wọ́n ń wá ojurere mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi nwọn ti gburo mi, nwọn o gbà mi gbọ́: awọn ọmọ àjeji yio fi ẹ̀tan tẹ̀ ori wọn ba fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wéré ti wọ́n gbọ́ ohùn mi, wọ́n gbọ́ gbàmí; àwọn ọmọ àjèjì yóò fi ẹ̀tàn tẹríba fún mi.