Psalms 18:49 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ni èmi ó ṣe máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, OLUWA, èmi ó sì máa kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li emi ṣe fi iyìn fun ọ, Oluwa, li awujọ awọn orilẹ-ède, emi o si ma kọrin iyìn si orukọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Títí láéláé èmi yóò máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, ìwọ OLÚWA; Èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ Rẹ.