Psalms 18:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ilẹ̀ ayé wárìrì, ó sì mì tìtì, ìpìlẹ̀ àwọn òkè mì jìgìjìgì; wọ́n wárìrì nítorí tí ó bínú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ilẹ mì, o si wariri: ipilẹ òke pẹlu ṣidi, o si mì, nitoriti o binu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ayé wárìrì, ó sì mì tìtì pẹ̀lú, ìpìlẹ̀, àwọn òkè gíga sì sídìí; wọ́n wárìrì nítorí tí ó ń bínú.