Psalms 19:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n wuni ju wúrà lọ, àní ju ojúlówó wúrà lọ; wọ́n sì dùn ju oyin, àní, wọ́n dùn ju oyin tí ń kán láti inú afárá lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn jù wura daradara pupọ; nwọn si dùn jù oyin lọ, ati riro afara oyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ṣọ̀wọ́n ju gólùù lọ, ju góòlù tí o dára jùlọ. wọ́n dùn ju oyin lọ, Àti ju afárá oyin lọ.