Psalms 19:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pẹlupẹlu àwọn ni wọ́n ń ki èmi iranṣẹ rẹ, nílọ̀, èrè pupọ sì ń bẹ ninu pípa wọ́n mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu nipa wọn li a ti ṣi iranṣẹ rẹ leti; ati ni pipamọ́ wọn ere pipọ̀ mbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípa wọn ni a ti sí ìránṣẹ́ Rẹ̀ létí; nípa pípa wọ́n mọ́, èrè púpọ̀ ń bẹ.