Psalms 19:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti apá kan ojú ọ̀run ni ó ti ń yọ wá, a máa yípo gbogbo ojú ọ̀run dé apá keji; kò sì sí ohun tí ó bọ́ lọ́wọ́ ooru rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ijadelọ rẹ̀ ni lati opin ọrun wá, ati ayika rẹ̀ si de ipinlẹ rẹ̀: kò si si ohun ti o fi ara pamọ́ kuro ninu õru rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjáde lọ Rẹ̀ ni láti òpin ọ̀run wá àti àyíká Rẹ̀ sì dé ìpínlẹ̀ Rẹ̀; kò sì sí ohun tí ó pamọ́ kúrò nínú oore Rẹ̀.