Psalms 2:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, yóo sọ̀rọ̀ sí wọn ninu ibinu rẹ̀, yóo dẹ́rùbà wọ́n gidigidi ninu ìrúnú rẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni yio sọ̀rọ si wọn ni ibinu rẹ̀, yio si yọ wọn lẹnu ninu ibinujẹ rẹ̀ kikan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó bá wọn wí ní ìbínú Rẹ̀ ó sì dẹ́rùba bà wọ́n ní ìrunú Rẹ̀, ó wí pé,