Psalms 2:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bèèrè lọ́wọ́ mi, èmi ó sì fún ọ ní àwọn orílẹ̀-èdè, gbogbo ayé yóo sì di tìrẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bère lọwọ mi, emi o si fi awọn orilẹ-ède fun ọ ni ini rẹ, ati iha opin ilẹ li ọrọ̀-ilẹ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Béèrè lọ́wọ́ mi, Èmi yóò jẹ́ kí orílẹ̀ èdè di ìní Rẹ, òpin ilé ayé yóò sì jẹ́ ogún Rẹ.