Psalms 20:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn óo kọsẹ̀, wọn óo sì ṣubú, ṣugbọn àwa óo dìde, a óo sì dúró ṣinṣin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn wolẹ, nwọn si ṣubu: ṣugbọn awa dide awa si duro ṣinṣin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n wólẹ̀, ní eékún, wọn sì ṣubú, ṣùgbọ́n àwa dìde, a sì dúró ṣinṣin.