Psalms 21:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O óo pa àwọn ọmọ wọn run lórí ilẹ̀ ayé, o óo sì run ìran wọn láàrin àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eso wọn ni iwọ o run kuro ni ilẹ, ati irú-ọmọ wọn kuro ninu awọn ọmọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀, àti irú ọmọ wọn kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.