Psalms 21:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O óo jó wọn run bí iná ìléru, nígbà tí o bá yọ sí wọn. OLUWA yóo gbé wọn mì ninu ibinu rẹ̀; iná yóo sì jó wọn ní àjórun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o ṣe wọn bi ileru onina ni igba ibinu rẹ: Oluwa yio gbé wọn mì ni ibinu rẹ̀, iná na yio si jó wọn pa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ìwọ bá yọ ìwọ yóò mú wọn dàbí ìnà ìléru. OLÚWA yóò gbé wọn mì nínú ìbínú Rẹ̀, àti pé iná Rẹ̀ yóò jó wọn run.