Psalms 22:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ ni wọ́n bí mi lé lọ́wọ́; ìwọ ni Ọlọrun mi láti ìgbà tí ìyá mi ti bí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ li a ti fi mi le lọwọ lati inu iya mi wá: iwọ li Ọlọrun mi lati inu iya mi wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ni a fi mí lé lọ́wọ́ láti inú ìyá mi wá nígbà tí ìyá a mí sì ti bí mi, ìwọ ni Ọlọ́run mi