Psalms 22:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo ayé ni yóo ranti OLUWA wọn yóo sì pada sọ́dọ̀ rẹ̀; gbogbo ẹ̀yà àwọn orílẹ̀-èdè ni yóo sì júbà níwájú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo opin aiye ni yio ranti, nwọn o si yipada si Oluwa: ati gbogbo ibatan orilẹ-ède ni yio wolẹ-sìn niwaju rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo òpin ayé ni yóò rántí wọn yóò sì yípadà sí OLÚWA, àti gbogbo ìdílé orílẹ̀ èdè ni wọn yóò jọ́sìn níwájú Rẹ̀,