Psalms 22:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn óo máa kéde ìgbàlà rẹ̀ fún àwọn ọmọ tí a kò tíì bí, pé, “OLUWA ló ṣe é.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o wá, nwọn o si ma sọ̀rọ ododo rẹ̀ fun awọn enia kan ti a o bí, pe, on li o ṣe eyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò polongo òdodo Rẹ̀ sí àwọn ọmọ tí a kò tí ì bí, wí pé òun ni ó ṣe èyí.